Isori oro ninu gbolohun ede yoruba lesson. SSS1 Second Term Yoruba Language .
Isori oro ninu gbolohun ede yoruba lesson Amuye ewi, koko ewi abbl. ISE ORO ORUKO NINU GBOLOHUN Oluwa (Subject): Oluwa ni oluse isele inu gbolohun. Eto aabo ilu ati ipati awon obinrin n ko ninu eto ogun . Oro Oruko tabi Ede: Atunyewo isori oro. Gbolohun eleyo oro ise, gbolohun olopo oro-ise, sise akojopo gbolohun eleyo oro-ise. A ko gbodo mu gbolohun ni okookan lati tumo, sise bee yoo so ewa ati itumo iru ayoka bee nii. NEW Yoruba Scheme of work for SSS 2 (organized in respective terms) SSS3 Yoruba Scheme of Work – 1st Term and 2nd Term. Awon isori ninu gbolohun ni awon wonyi : Oro oruko, Oro aropo oruko , Oro ise, Oro apejuwe, Oro aponle, Oro asopo, Oro atokun. Ose keta Awon isori gbolohun Yoruba gege gi ise won SSS1 Second Term Yoruba Language Apola je okan ninu awon abala ihun gbolohun ede Yoruba. Apole ise iii. Asa: Asa iranra-eni lowo. See also. Nonba. Mama se isu ewura. Bi a ba yo oro-ise kuro ninu awon Eko Ede Yoruba Titu Iwe Kininni (JS1) by Oyebamiji Mustapha et al Lesson Notes; Exam Questions; E-textbooks; Lesson Plans; Lesson Notes; E-Textbooks; After School; Scheme of Wok; Exam Questions; Opening Hours. Akekoo yoo le: Daruko awon isoro oro yorùba; Toka si isori kookan ninu gbolohun. Apeere; Kunle pa ejo Oluko koi se si oju patako ii. apeere Bisi je iyan ni owuro gun Lesson note on Yoruba for SS2 Third Term - Edudelight. Apeere: - Awon eniyan mo pe ounje won Bisi daba a moto rira Alaga feiyawo Koko Ise wa toni ni:EYA GBOLOHUN EDE YORUBA NIPA IHUN(1) Gbolohun Eleyo Oro Ise: Eyi kii ni ju oro ise kan pere. com YORUBA LANGUAGE J. Ohun ti eka ede je ii. View > 11 LETA KIKO. Download Comprehensive Senior Secondary School Lesson Notes for Yoruba Language SSS2 2nd term in PDF or DOCUMENT - Edudelight Store EDE – Apola ninu gbolohun ede Yoruba: i. Oro atokun viii. Salaye meji ninu won pelu apeere. Ninu Ede Yoruba mefa EKA ISE: EDE AKOLE ISE: ISORI ORO NINU GBOLOHUN Isori oro ni abala ti a pin awon oro inu ede yoruba si. Oro-oruko kan soso pere. Bi a ba yo oro-ise kuro ninu awon Click to read:AKOLE ISE: ISORI ORO NINU GBOLOHUN - Discover insightful and engaging content on StopLearn Explore a wide range of topics including Notes. Isesi oro aropo afarajoruko ko yato si ti oro oruko. Gbolohun Yoruba JSS 1 First Term Lesson Notes. LITIRESO – Itupale asayn iwe lati ajo WAEC/NECO yan: 3 Apola je okan ninu awon abala ihun gbolohun ede Yoruba. Oro oruko ii. Apola le je eyo oro kan, o si le je meji tabi ju bee lo. OSE KERIN. Apola – oruko le je eyikeyii ninu awon wonyi. Iwulo Ede Yoruba; Litireso Alohun to je mo esin; Week 7 – Onka Yoruba lati ookan de aadota (1-50) Bi asa se jeyo ninu ede Yoruba; Litireso Apileko Ose kin-in-ni Ede-Atunyewo awon isori oro ninu ede Yoruba. Titi se obe. Apola Oruko le je: Oro Oruko eyo kan ni ipo oluwa tabi ni ipo abo. ORI ORO: ISE ORO ISE NINU GBOLOHUN. Oro Ise Elela:Gege bi oruko re n je oro ise nla si meji ninu gbolohun ti a ti loo , ti aa o si fi oro Milan boo laarin. Onka lati ookan lelaadota de ogorun-un (51-100) Asa ati ohun-elo isomoloruko. Apeere: Tisa ka iwe. O wa. Ipo meta ni oro oruko le ti jeyo ninu gbolohun. Asà, Edè Ati Litireso II 11 Topics Expand. Bi a ba yo oro-ise kuro ninu awon Koko Ise: Ise oro Ise ninu gbolohun. Bi apeere: 1. Bi apeere:-Dupe 'pon' omi. iii. Isori oro Yoruba oro-oruko (NOUN) oro-aropo oruko (PRONOUN) oro ise (VERB) oro Aropo afarajoruko oro atoku A le lo oro aropo oruko gege bi eya ati opo ni ipo eni kin-in-ni, eni keji ati ipo eni keta. Orisirisi ona ni a n gba gbe iyawo. Won wo aso, won si wo bata. Oriki. Asa: Asa iranra-eni lowo . Apeere:Ile woO waAwa naa je eba metameta. Kin ni iseda oro-oruko? Daruko ona ti a n gba seda oro- oruko . Ikini II Akoko; Litireso alohun to je mo Aseye; Week 6 – Akoto awon oro ti a sunki . Oro – ise ni opomulere gbolohun ede Yoruba, la i si oro-ise, irufe gbolohun bee yoo padanu SECOND TERM E-NOTE SUBJECT; YORUBA. Apola oro oruko ni eyo oro oruko kan tabi meji tabi ju OSE KETAORO ISE. apeere. ----- OSE KEFAORI-ORO-;SISE AYOKA EDE GEESI SI EDE YORUBA ASA ORI-ORO-; IGBEYAWO ODE-ONI IGBEYAWO SOOSI IGBEYAWO MOSOLASI IGBEYAWO KOOTULode oni, aye ti di amulumala. Die lara apere ni oro-oruko, oro-ise, ati bee lo. Free secondary school, High school lesson notes, classes, videos, 1st Term, 2nd Term and 3rd OSE KETAAPOLA – ORUKOAKOONUAPOLA ORUKO:- Ni oro tabi akojopo oro to le duro gege bi Oluwa, abo pelu eyan tabi laisi eyan ninu gbolohun. Apeere:Femi waSola sun. y. Apeere: Ede: Atinyewo awon isori oro: Ni opin idanilekoo, awon akekoo yoo le: i. Oro- oruko pelu awe gbolohun . Won n rin, won n yan, won si n se oge. Fadeke n jenu waduwadu. Asa: Igbeyawo isinku ati ogun Jiye Litireso: Ewi Apileko. 04 ISORI GBOLOHUN OLOPO ORO-ISE . Awon akekoo salaye oriki oro Awon akekoo sapejuwe awon isori oro inu gbolohun ati ise ti won n se pelu apeere orisirisi labe okookan. Awon litireso apileko ewi. AKORIN EKO: ISEDA ORO{ISODOURKO} Ifaara: Isodoruko ni sisedia oro-oruko. Atoka/wuren gbolohun onibo ni: ti, ki,iba,ni,pe,nigba,bi. Irufe oro-aponle inu ede Yoruba pin si orisii meji. Orisirisi ona ni a le pin gbolohun ede Yoruba si, Awon ni: gbolohun eleyo oro ise, EDE – Itesiwaju eko lori isori gbolohun gege bi ihun won. ( – Listen to EYA GBOLOHUN EDE YORUBA NIPA IHUN by Yoruba Educational Series instantly on your tablet, phone or browser - no downloads needed. 1. Awon naa ni awe gbolohun afarahe ati olori awe gbolohun. Sade 'ra' bata. Awe gbolohun pin si orisii meji. Eyi ni awon gbolohun gege bi ihun won; Gbolohun eleyo oro-ise Gbolohun olopo-oro-ise Gbolohun alakanpoGbólóhùn eleyo oro-ise-: ni gbolohun ti o maa n ni eyo oro ise kan Eko ti o je mo bi a se n to iro papo ninu oro ede Yoruba ti oro ede Yoruba si fi yori si gbolohun ede Yoruba ni a n pen i fonoloji. Iro Faweli: Eyi ni awon iro ti a maa n gbe jade nigba ti ko si idiwo fun eemi ti o n ti inu edo foro oo. (2) Gbolohun Olopo-Ise: Irufe gbolohun yi maa n ni ju oro ise kan lo. Igbeyawo soosi yii fese mule laarin awon onigbagbo, igbeyawo mosalasi si Bi asa se jeyo ninu ede Yoruba. ORISIIRISII GBOLOHUN OLOPO ORO-ISEGbolohun olopo oro-ise 'Gbólóhùn èdè Yorùbá ni a lè pè ní odidi ọ rọ tí ó pé, tí ó ní olùṣe ati abọ nínú tí ó sì bẹ rẹ pẹ lú lẹ tà ńlá. Awe gbolohun je ipede to ni oluwa ati ohun ti oluwa se (oro-ise). Awon iran/orile ti o maa n jagun ni ile Yoruba laye atijo. Oro-oruko ii. Ninu gbolohun, a maa n ri orisirisi isori oro paapaa julo oro ise gege bi opomulero gbolohun. Ibere gbolohun ni o saba maa n wa. 3 Copromutt Publishers. Awon isori oro ti a le ba pade labe apola oruko ati apola ise . ose kokanla ati ikejila: ede: atunyewo eko lori iseda oro . ‘O je e. OSE KERINISORI GBOLOHUN OLOPO ORO-ISEAKOONUGbolohun Olopo Oro- ise ni gbolohun ti o maa n ni ju oro-ise kan lo, o le je meji meta tabi ju bee lo. Bawi: Tisa ba ojo wi fu oju kokoro re EDE – Itesiwaju eko lori isori gbolohun gege bi ihun won. Stay informed, entertained, and inspired with our carefully crafted articles, guides, and resources. a Mo A O E O Won ENI IYE EYO OPO Eni kin in ni mo a Eni keji o e Eni keta 0 won LILO ORO AROPO ORUKO NINU GBOLOHUN Mo je isu A ti de Eko yii salaye orisirisi Isori Oro to wa ninu Ede Yoruba pelu awon apeere. Y (2009) IMO, EDE, ASA ati LITIRESO YORUBA J. Asa:Elegbejegbe tabi iro-siro. ori oro: aroko alapejuwe. Asa : Isinku nile Yoruba. Apeere: Ile wo. Oro Asopo Oro-oruko: Eyi ni awon oro ti won le da duro ni ipo Oluwa, abo tabi eyan ninu gbolohun. OSE KETAAPOLA-ISE(verb phrase)Ninu apola-ise ni koko gbolohun maa n wa. Ihun orisirisi awe gbolohun po lati di odidi gbolohun, Aroka alalaye, Gbolohun Onibo Monday , 23 December 2024 Trending Learn Yorùbá with ÌféolúwaPart of speech in Yorùbá/Ìsòrí òrò gbólóhùn èdè YorùbáThanks for watchingplease don't forget to subscribe, like and share. Monday – ORO – ISE (VERB): Isori oro yii ni o maa n tola ohun ti oluwa se tabi toka isele ninu gbolohun. CLASS-; SS1 ILANA ISE OSOOSE FUN SAA KEJI Ose kinni- Ede-Atunyewo awon isori oro oro aropo oruko oro aropo afarajoruko oro atokun oro asopo oro-ise Asa- Oge sise Litireso-Itupale asayan iwe litireso Ose keji Ede- Awon isori gbolohun gege bi ihun won. ASA ELEGBEJEGBE. 2 Ede: Aroko alalaye Asa: Ogun pinpin Litireso: Awon ewi alohun to je mo esin abalaye. Oro –oruko ni awon oro ti won le da duro nipo oluwa,abo tabi eyan ninu gbolohun. EDE – Apola ninu gbolohun ede Yoruba: i. O maa n toka isele inu gbolohun laaarin oluwa ati abo(oro ise kikun). Litireso je ona ti Yoruba n gba fi ero inu won han nipa iriri won gbogbo. EDE – Itesiwaju eko lori isori gbolohun gege bi ihun won. ----- Ose kin-in-ni Ede-Atunyewo awon isori oro ninu ede Yoruba. ORO – ISE (VERB): Isori oro yii ni o maa n tola ohun ti oluwa se tabi toka isele ninu gbolohun. Aroko atonisona Alapejuwe; Oye jije ati ohu elo oye jije. Oriki Olori Awe Gbolohun (Isori Awe Gbolohun) Awe Gbolohun Afarahe Orisii Awe Gbolohun Afarahe. Apeere:Dolapo ra keke. A personalized learning resource for all agesClassNotes. Gbolohun olopo oro-ise naa ni a mo si gbolohun onibo. ILO ORO AROPO ORUKO NINU GBOLOHUN ASA: IPOLOWO OJA . Isori oro +ninu gbolohun ATUNYEWO GBOGBO ISORI GBOLOHUN Gbolohun le je eyo oro tabi akojopo oro ti o ni oro-ise ninu. Ede: Aayan Ogbufo. Lara apola inu ede Yoruba ni apola oruko, aopla ise, ati apola aponle. IHUN APOLA ORUKOApola – oruko le je eyikeyii ninu awon wonyiOro-oruko kan soso pereOro aropo-orukoOro aropo-afarajorukoOro – oruko pelu eyan Click to read:Ori Oro: Isori Oro - Oro Aropo- Afarajoruko - Discover insightful and engaging content on StopLearn Explore a wide range of topics including . A n gbe iyawo ni ile Olorun, a n gbe e ni kootu, a si n gbe ni mosalasi. ABUDA FUN ISAPEJUWE IRO KONSONANTIEyi ni awon abuda ti a maa tele ti a ba fe sapejuwe iro konsonanti Ipo ti alafo Isori oro ninu ede Yoruba Isori oro ninu ede Yoruba ni wonyii i. Ise Oro Ise:Oro Ise ni o maa n toka isele inu gbolohun. Fun apeere. A fún àwon gbólóhùn Yorùbá ní orúkọ gégé bí íse tí won ń se. ETO ISE FUN SAA KEJI. Ose keta Awon isori gbolohun Yoruba gege gi ise won Grab your copy of Second Term Eko yii salaye orisirisi Isori Oro to wa ninu Ede Yoruba pelu awon apeere. Awe gbolohun Ede Yoruba ni gbolohun onibo. AWON APOLA INU EDE YORUBA 1. Awon litir//so Apileko – Ere onitan. OSE 3 ISORI GBOLOHUN – EduDelightTutors NERDC Curriculum Yoruba SS1 SS1 Second Term Yoruba Curriculum Lagos State. LIT: Itupale ewi apileko. apeereO lo [ eyo ni o ]Won wa [ opo ni won] oro FIRST TERM E-LEARNING NOTE SUBJECT: YORUBA LANGUAGE CLASS: JSS3 1 Ede: Atunyewo fonoloji ede Yoruba. LITIRESO – Itupale asayn iwe lati ajo WAEC/NECO yan: 3 SECOND TERM E-NOTE SUBJECT; YORUBA. Yoruba lesson notes for SS1 Second Term – Edudelight. FONOLOJI EDE YORUBA. Irufe gboloun yii maa n ni ju eya kan lo. Tolu fo aso. litireso: kika iwe ewi ti ijoba yan. Dahun Ibeere to jeyo ni abala yi. Ra ati fo lo je oro–ise ti a fi mo OSE KEJIAPOLA ORUKO (Phrases)Apola ni apa kan gbolohun ti o le je oro tabi akojopo oro. AKOONUAwe gbolohun je ipede to ni oluwa ati ohun ti oluwa se (oro-ise). Awon isori oro ti a le ba pade labe apola oruko ati apola ise. Eyin oro-oruko ti o n ya n ni oro-apejuwe maa n wa. Kii se gbogbo oro inu ede kan naa le tumo si ode miiran. Bi apeere: Bawi, baye, pade. Àbùdá Òrò ìse àti Òrò atókùn jora púpò láti fí so pé Òrò ìse ni, sùgbón ìsòrí Òrò tí ó dá dúró ni Òrò atókùn jé. Osa keji OSE KEJIEDE GBOLOHUN ONIBOAKOONU Oriki gbolohun onibo Apeere atoka/wuren gbolohun onibo Apeere gbolohunNi opo igba a maa n pe gbolohun onibo ni gbolohun olopo oro ise tabi gbolohun alakanpo. Eto aabo ilu ati ipati awon obinrin n ko ninu eto ogun. Follow me OSE KERINAKORI ORO: - EYA GBOLOHUN EDE YORUBA AKOONU: -- Gbolohun eleyo oro ise - Gbolohun olopo oro ise - Gbolohun alakanpo - Gbolohun ase - Gbolohun ibeere Gbolohun ni ipede ti o kun. Download Comprehensive Senior Secondary School Lesson Notes for Yoruba Language SS2 2nd term in PDF or DOCUMENT - Edudelight Store EDE – Apola ninu gbolohun ede Yoruba: i. Asa: Asa araraenilowo: Ni opin idanilekoo, åwon akéköö yoo le: i. Oro Aponle ati Apola Aponle, titoka si ilo oro aponle ninu gbolohun, fifa oro aponle ati apola aponle yo ninu AKOLE ISE: ISORI ORO NINU GBOLOHUN Isori oro ni abala ti a pin awon oro inu ede yoruba si. Iro faweli ati iro konsonanti aranmupe asesilebu ni o maa n sise gege bi odo silebu. ose keje: ede: itupale gbolohun onipon-on-na. ’ ‘ ojo ro’. Orisiirisii ni awon eya gbolohun ti o wa ninu ede Yoruba. Editable and printable. Oro aponle ni a n lo lati yan tabi se afikun itumo fun oro ise tabi apola-ise ninu gbolohun. Oro aponle vii. O je ipede ti ko ni ju apola-oruko ati apola-ise EDE – Itesiwaju eko lori isori gbolohun gege bi ihun won. Gbólóhùn jé ìsọ tí ó ní ìtumo kíkún. AP. ORO APEJUWE: otun le je oro eyan o si ma n fi o le le ori oro-oruko ninu apola oruko ninu ede Yoruba. AKOONUOro aropo oruko ni a maa n lo dipo oro-oruko ninu apola oruko. The lesson notes, videos and interactive slideshows are built on curriculum that is designed to meet national and international O’ Level standard for Senior High School or Senior Secondary school students (SS1, SS2, SS3 or SHS1, SH2, SH3) and Grade 9, Grade 10, Àlàyé lórí Òrò atókùn ń gbé òwe Yorùbá léyìn pé '' bí a bójú tí a bómú, ìsàlè àgbòn làá Parí rè sí ''. Oro ise ni opomulero gbolohun. 1: Ookan: 2: Eeji: 3: Eeta: 4: gbolohun. EDE: Oro Aropo-Oruko ASA: Yoruba lesson for JSS3 (Basic 9) - Edudelight. Osa keji — Ede-Awon isori gbolohun ede Yoruba gege bi ihun. Àwon òrò- ìṣẹ náà nìwònyí: Click to read:Akole Ise:- Ede:- Awon isori gbolohun Yoruba gege bi ise won. Eya gbolohun nipa ise won Asa igbeyawo ni ile Yoruba Kika iwe apileko ti ijoba yan 3. Oro Aponle vii. Isori oro lede yoruba Ni opin idanilokoo, awon akekoo yoo le: i. Ojo ko leta. 5 ÈDÈ: Onka Yoruba lati ookan de aadota [1-50]. Adebisi n soro fatafata ni kilaasi. oriki; orisi oro oruko; ise ti oro oruko n se ninu ninu gbolohu; asa: asa isomoloruko ni ile yoruba. Ninu awon gbolohun oke, ayewe-idanwo wo fala 1. Litireso Apileko: Eyi ni litireso ti a se akosile ni gba ti imo moo- ko – moo-ka de. IWE AKATILEWA Eko ede ati asa Yoruba. Àsà, Edè Ati Litireso I – Asa: Iwa omoluabi – Ede: Atunyewo leta aigbagbefe – Ede: Atunyewo isori oro The recommended textbooks for Yoruba in J. ose kefa: ede: isori oro. Awon ni oro ipile ati oro atowoda tabi oro ti a seda. Apeere:Mo jeun mo si yo. asa: atunyewo asa ikini ni ile yoruba litireso: atupale iwe ewi ti a ka ose kin-in-ni. Free secondary school, High school lesson notes, classes, videos, 1st Term, 2nd Term and 3rd OSE KEWAAORI-ORO-;ISORI ORO-ORUKOAKOONU- oriki- orisiirisii oro oruko. Apola oruko ii. Oro ise ni koko fonran to n toka isele tabi nnkan ti oluwa n se ninu gbolohun. Week 6 – Akoto awon oro ti a sunki . Fun Apeere Wa-je oro onisilebu kan nitori pe ami ohun kan ni o wa lori re. Ogiri ile ti wo lule EDE – Itesiwaju eko lori isori gbolohun gege bi ihun won. Yoruba bo, wo ni bi eye ba se fo ni a oo se so oko re. Gbolohun ase 5. Bolu fo aso. EKA ISE: EDE. Oro aropo afarajoruko iv. Ose kin-in-ni Ede-Atunyewo awon isori oro ninu ede Yoruba. Àpeere: Bólá sùn Adémide jéìrẹsì. - Discover insightful and engaging content on StopLearn Explore a wide range of topics including Notes. Orisirisi ona ni ihunoro tabi silebu lee gba waye ninu ede yoruba. Awon oro-aponle aseda. O maa n se afikun itumo fun apola-ise, ti yoo si je ki itumo re si tubo ye ni yekeyeke. SILEBU EDE YORUBA. Litireso: Itupale iwe aseyan ti an ka. Oro –ise Agbabo : – ni oro-ise ti a maa n lo abo pelu re ninu edeap ‘Tolu sun’ Tope kuru. Awon isori-oro ni a fi n hun gbolohun nitori pe ise ti oro ba se ninu gbolohun ni a le fi mo iru isori-oro ti n se. - lilo oro oruko ninu gbolohun. Gbolohun Ibeere 4. Learning Yoruba helps students improve their communication, critical thinking, and appreciation of b. Ng offers practice exercises, lesson, and a personalized learning dashboard that empower learners to study at Free Yoruba online learning lesson notes and videos for Secondary school and High school students. LITIRESO – Itupale asayn iwe lati ajo WAEC/NECO yan: 3 Yoruba bo, wo ni bi eye ba se fo ni a oo se so oko re. Iroyin OSE KEJIAPOLA ORUKO (Phrases)Apola ni apa kan gbolohun ti o le je oro tabi akojopo oro. Gbolohun iba/kani 8. Oro ise v. Won ni eto eni ati iye b. ISE ORO ISE NINU GBOLOHUN. Apola Oro – oruko (Noun Phrase): Eyi le je oro ISE-:EDE YORUBA CLASS: SS1 ILANA ISE OSOOSE FUN SAA KETA Ose: EDE: Isori oro;Oro Oruko: Oriki, Orisii Oruko, Ise Oro-Oruko ninu Gbolohun ASA: Asa- Asa Isomoloruko: Amutorunwa, abiso, inagije abbl. Gbólóhùn ni ìpèdè tí ó kún, tí o sí ní ìse tí ó ń jé. OSE 3 OSE KETAORO ISE. Ise oro-aponle ni lati se afikun itumo fun apola-ise ninu gbolohun lati mu ki itumo re yeni yekeyeke si bi apeere: Tun n rin werewere lo si ile. Síńtáàsì ni èka kan nínú gírámà èdè tí ó níí sè pèlú bi a se ń so òrò pò tí ó fi ń di gbólóhùn àti bí a se ń fún gbólóhùn yìi ní ìtumò. Isori oro +ninu gbolohun ORO – ISE (VERB): Isori oro yii ni o maa n tola ohun ti oluwa se tabi toka isele ninu gbolohun. Olori Awe Gbolohun: Olori awe gbolohun ni abala apakan odindi gbolohun ti o le da duro pelu itumo. Oro Atokun viii. Ori re ni oro ise maa n dale lori. IHUN APOLA ORUKO. Awon ni ; NERDC Curriculum Yoruba SS1 SS1 Second Term Yoruba Curriculum Lagos State. Èyìí rí béè nítorí pé ohun tí a pè ní atókùn yìí jo ìsòrí Òrò ìse. Awon eka ede to wan i ipinle kookan 10 EDE – Apola ninu gbolohun ede Yoruba: i. Litireso Alohun: Eyi ni litireso ti a fi ohun enu gbe jade ti a jogun lati odo awon baba nla wa. Oro – ise ni opomulere gbolohun ede Yoruba, la i si oro-ise, irufe gbolohun bee yoo padanu itumo re. ORO-APONLE. Baba ko ebe. Aewoyin S. ASA – Igbagbo ati ero Yoruba nipa Ajinde leyin iku LITIRESO – Awon eka ede Yoruba: i. O le je faweli EDE – Itesiwaju eko lori isori gbolohun gege bi ihun won. Ogiri ile ti wo lule ISORI ORO . Won fun gbolohun ede Yoruba ni oruko gege bi ise ti o n se. Free secondary school, High school lesson notes, classes, videos, 1st Term, 2nd Term and 3rd Studying Yoruba in Junior Secondary School 3 (JSS3) gives students a deep understanding of the Yoruba language, literature, and culture, boosting their language skills and cultural awareness. Iji jaMo sunIyan naa kan Oro-ise ati oro-oruko ni ipo abo. Òrò-iṣe jé òpómúléró gbólóhùn( Pillar of a sentence). OSE KETAEDE AWE GBOLOHUNAwe gbolohun ni apakan odindi gbolohun. Oro Ise vi. ose karun-un: ede: aroko ajemo-isipaya asa: ere idaraya; ere igbalode. Apeere; Iyabo je isu; Adufe ka iwe Orisiirisii isori ni awon onimo girama pin oro ise si ninu ede Yoruba. - ise ti oro oruko n se ninu gbolohun. AKOONU. Asa- Oge sise Aso wiwo laarin okunrin ati - EDE – Itesiwaju eko lori isori gbolohun gege bi ihun won. Lara awon isori Salaye asa ikeru ri ile Yoruba; Ba wo ni a se n ki awon wonyi ni ile Yoruba; Eni to sese bimo; Alaro . Ise ti oro oruko n se ninu gbolohun Ipo ti oro oruko ba ti jeyo ninu gbolohun ni a fi n toka ise won i. Awon ni: i. AKOLE ISE: ONKA YORUBA LATI OOKAN DE AADOTA (1-50). Oun ni o maa n toka si ibasepo ti o wa laarin oluwa ati abo. oruko amutorunwa; oruko abiso mo esin tabi ise,idile,abiku abbl; oriki; inagije litireso: itupale ewi apileko. S. orisiirisii isori oro ni o le jeyo po ninu apola-ise. Eya gbolohun Asa igbeyawo ni ile Yoruba (igbeyawo ode-oni) Kika iwe apileko oloro geere 4. Litireso: kika iwe litireso ti ijoba yan. Oro –oruko ni awon oro ti won le da duro Orisirisi isori oro mejo ni o wa ninu ede Yoruba. d. Oro aropo-afarajoruko. Lesson Content 0% Complete 0/11 Steps Ede: Atunyewo Akaye. Orisii oro meji ni o wan i ede yoruba. LITIRESO – Itupale asayn iwe lati ajo WAEC/NECO yan: 3 APOLA ORUKO:- Ni oro tabi akojopo oro to le duro gege bi Oluwa, abo pelu eyan tabi laisi eyan ninu gbolohun. Ap. LSUS. ose kerin: ede: onka yoruba lati egbaa de egbaarun – un (2000-10,000) asa: ere idaraya Lara awon isori oro ti a to jo lati hun gbolohun ede Yoruba ni: Oro Oruko; Oro Aropo Oruko; Oro Apejuwe; Oro Ise; APOLA ORO ORUKO (NOUN PHRASE): Eyi le je oro kan tani akojopo oro ti a maa n lo gege bi oluwa ati abo ninu gbolohun yala pelu eyan tabi laisi eyan. OSE KEWAAORI-ORO-;ISORI ORO-ORUKOAKOONU- oriki- orisiirisii oro oruko. Apeere;Yetunde sun fonfonEpo wa ni Sapele. Oriki Abuda oro aropo oruko Ate oro aropo oruko Irisi oro aropo oruko. Orisii iro faweli meji ni o wa ninu ede Yoruba, awon ni: Weekly Lesson Notes Yoruba JSS 1 First Term AKOLE ISE – ALIFABETI YORUBA Ami Ohun lori awon faweli ati oro onisilebu kan. Oro Eyan / Apejuwe v. Gbolohun alakanpo 6. LITIRESO – Awon eka ede Yoruba: Ohun ti eka ede je; Awon eka ede to wan i ipinle kookan OSE 10. Eto aabo OSE KETAORO ISE. Isori oro Yoruba oro-oruko (NOUN) oro-aropo oruko (PRONOUN) oro ise (VERB) oro Aropo afarajoruko (PROMINAL) oro apejuwe ( ADJECTIVE ) oro atoku (PREPOSITION) oro asopo ( Subscribe- be the first to view our latest videos Connect with WazobiaMax TV on social media: Follow WazobiaMax TV on Secure your Second Term SS2 Yoruba lesson note with a quick payment process. Ihun apola iv. Free secondary school, High school lesson notes, classes, videos, 1st Term, 2nd Term and 3rd OSE KETAORO ISE. OSE KOKANLA EKA ISE: EDE AKOLE ISE: ISORI ORO NINU GBOLOHUN Isori oro ni abala ti a pin awon oro inu ede yoruba si. ```AKOONU: -Oro-ise ni oro ti o ba le duro bii koko fonran ninu gbolohunoro-ise ni oro ti o n toka si ohun ti oluwa se ninu gbolohun laisi oro ise ninu gbolohun ko le ni itunmo nitori ohun ni o je opomulero fun gbolohun. Salaye ise ti awon isori oro yii maa n se nbinu gbolohun. AKOLE ISE – ALIFABETI YORUBA. Awon isori oro ti a le ba pade labe apola oruko ati apola ise ASA – Igbagbo Yoruba nipa Olodumare: i. Gbolohun alaye 3. Ere Onise. Ori odo silebu ni a maa n fi ami ohun siKan-an-n-pa ni odo silebu je ninu ihun ose kin-in -ni: ede: isori oro- oro oruko. Orisiri apola lo maa n di apa kan tabi odidi gbolohun. salaye ipaa ti okookan ko ati iwulo wan ninu gbolohun Asa OSE KESAN-ANORO ORUKOOro oruko (noun) ni awon oro ti o n sise Oluwa, abo tabi eyan ninu gbolohun. ose keji: isori oro- oro aropo oruko. Abuda oro aropo oruko. fun isori oro ni oriki ii. Ko Isori gbolohun olopo oro-ise merin sile. Oro – oruko pelu eyan. apeere Bisi je iyan ni EKA ISE: EDE ORI ORO: ISORI –ORO (ORO- ORUKO) Ise ti oro Kan ba n se ninu gbolohun ni a le fi pin in si isori oro ti o ye ninu gbolohun. Ede:- Akaye Oloro Geere wuuru OSE KERINORI-ORO ; APEJUWE IRO KONSONANTIAKOONUIro konsonanti; ni iro ti a pe nigba ti idiwo wa fun eemi ti o ti inu edofooro bo. Awa naa je eba metameta. 3 include: Textbooks (JS1 -3) Eko Ede Yoruba Titu Iwe Kininni (JS1) by Oyebamiji Mustapha et al Eko Ede Yoruba Titun Iwe keji (JS2) by Oyebamiji Mustapha et al Litereso atI Asa Yoruba JS3 by Mobolaji Arowosegbe Litereso Texts Sisi Oloja by Olajumoke Bamiteko Subu Sere by Lasunkanmi Tela OSE KETAAPOLAAKOONU: - Ki ni a n pe ni apola Ki ni apola oro oruko Ise ti apola oro oruko n se ninu gbolohun Ki ni a n pe ni apola ise Ise ti apola ise n se ninu gbolohunApola ni akojopo oro ti o n di apa kan gbolohun. 2 Eto ise fun saa keji Ose kin-in-ni: Ede-atuyewo ise saa kin-in-ni (onka 201-500) Asa-atuyewo ise saa kin-in-ni (asa isomoloruko) OSE KEJIORI-ORO- AWON ISORI GBOLOHUN GEGE BI IHUN WON. OSE KARUN-UN. 1. itupale pon-on-na; dida gbolohun mo Our mission is to provide a world‑class education for anyone, anywhere. Akanbi gun igi rekoja ewe. OSE KEJE. Tobi jeun dieBolu n rin kanmokanmo bo. Pay using ATM, USSD, or bank transfer and download the document instantly. Litireso: Itupale iwe aseyan ti an ka Osa keji Ede-Awon isori gbolohun ede Yoruba gege bi ihun. Oro – ise ni opomulere gbolohun ede Yoruba OSE KERINISORI GBOLOHUN OLOPO ORO-ISEKo si bi eniyan se le wa ti ko ni se amulo gbohun bi ti wule ki o ri, eeyan gbodo se amulo gbolohun ayafi ti eniyan ba je odi loku. Osa keji Isori oro +ninu gbolohun; Isinku nile Yoruba . AKORI ISE (ASA): ASA IRANRA OSE KEFAORO – APONLEAKOONUOro-Aponle je oro ti o maa n pon oro-ise ninu gbolohun. Sise atunyewo fonoloji ede Yoruba Atunyewo awon asa ninu ise olodun kin-in-ni Atunyewo awon ewi alohun yoruba 2. Gbolohun gbodo bere pelu leta nla, ki o si pari pelu ami idanudoro. So ise ti okookan n se ninu gbolohun Isori oro ni abala ti a pin awon oro inu ede yoruba si. Olu n 'ro' amala ni ori ina. Litireso Apileko. Gbolohun ni a fi maa n se agbekale ero okan wa kale. Gbolohun re je eyo oro kan tabi akojopo. Oro Aropo Afarajooruko iv. Oro aropo oruko ni eto to n toka si iye bi eyo tabi opo. To Order now for instant access, Click Here. Iru oro bee ni rakorako, fiofio, tonitoni. Ijala, - Ose kin-in-ni Ede-Atunyewo awon isori oro ninu ede Yoruba Asa:Elegbejegbe tabi iro-siro Litireso: Itupale iwe aseyan ti an ka Osa keji Ede-Awon isori gbolohun ede Yoruba gege bi ihun Asa: Asa iranra-eni lowo Litireso: kika iwe OSE KARUN-UNAWE GBOLOHUN EDE YORUBA. OSE KESAN-ANOri-oro-; Aroko oniroyinAkoonu:Aroko oniroyin:- je mo iroyin sise tabi itan isle ti o ti koja seyin ti o si se oju eni ti a n royin re ni sise-n-tele ninu aroko oniroyin fun elomiran ti ko si nibe. Ní àtàrí pé a ò lè má rí i nínú èrò tí a pè ní gbólóhùn, àwon òmòràn nínú èdè Yorùbá ti ki ìsòrí yìí bi òpómúléró. ’ ‘ewure je agbado Bola’ ‘ewure je agbado re. Silebu/ihun oro lee waye gege bi faweli. litireso: itupale asayan iwe ti ijobayan. Oro – oruko Oro aropo – oruko Oro – ise Oro apejuwe Oro aponle Oro asopo abbl. iv. Lai si oro ise ninu gbolohun, gbolohun ko le ni itumo. O le je oruko eniyan, eranko, ibugbe, ibikan tabi nnkan. AKOLE ISE: ISORI ORO NINU GBOLOHUN Orisiirisii isori ni awon onimo girama pin oro ise si ninu ede Yoruba. com SECOND TERM YORUBA LANGUAGE SS ONE ETO ISE FUN SAA KEJI Ose kin-in-ni Ede-Atunyewo awon isori oro ninu ede Yoruba ORO – ISE (VERB): Isori oro yii ni o maa n tola ohun ti oluwa se tabi toka isele ninu gbolohun. ASA – Eto ogunjije. Apeere: Aso re po n rakorako. asa: owe ile yoruba. . Oro Ise ni emi gbolohun. Food Safety Social Studies Primary 1 Second Term Lesson Notes Week 10; 2 EDE – Itesiwaju eko lori isori gbolohun gege bi ihun won. Oro aropo oruko iii. I / we = 2 EKA ISE: EDE ORI ORO: AWE GBOLOHUN EDE YORUBA Gbolohun onibo ni gbolohun ti a fi gbolohun miiran bo inu re. Ede:- Akaye oloro geere. Ap Tolu sun. Litireso: itupale asyan iwe aroso meji. ORO – AYALO. apeere ‘Bolu je akara. S. Oro apejuwe vi. Ile naa mo tonitoni. Oriki ati liana kiko aroko Yoruba pelu apeere; Isomoloruko II. Iro konsonanti mejidinlogun lo wa ninu ede Yoruba awon naa ni b,d,f,g,gb,h,j,k,l,m,n,p,r,s,s,t,w. JSS 2 FIRST TERM LESSON NOTE YORUBA. Sålåyé itumo åså Koko Ise: Ise oro Ise ninu gbolohun. Fonoloji ni imo eto amulo iro lapapo. Oro oruko n sise abo: eyi ni olufaragba ohun ti oluwa se ninu gbolohun. -Oriki Iwulo oro ise Ona ti a le gba lati da oro ise mo. Oro Aropo oruko iii. So awon isori oro ti o wa ninu gbolohun ede Yoruba ii. Gbolohun ede Yoruba nipa fifi oju ihun wo o Sise akanse ise awujo Yoruba (project) Litireso alohun to je mo ayeye Onka Yoruba (101-300) Ise akanse kan ni awujo (project) Litireso alohun to je mo ayeye Kika iwe apileko ti ijoba How much of the Yoruba Language do you understand? Stay connected to this channel as we promise to bring you more tutorials on Yoruba Language. Fa örö eyån yo ninu gbolohun ii. Igi osan naa ga fiofio. Oro ipile: Eyi ni awon oro ti a ko le seda won. Click to read:Akole Ise:- Ede:- Awon isori gbolohun Ede Yoruba Gege bi Ihun - Discover insightful and engaging content on StopLearn Explore a wide range of topics including . Eko ti o je mo bi a se n to iro papo ninu oro ede Yoruba ti oro ede Yoruba si fi yori si gbolohun ede Yoruba ni a n pen i fonoloji. Ise Asetilewa:- Ko bi a se n ki awon wonyin ni ile Yoruba (a) Amokoko (b) Ahunso (d) alagbede (e) apeja . Isori oro Yoruba ni wonyii; Oro oruko(noun) Oro ise(verb) Oro aropo oruko(pronoun) Litireso ni akojopo ijinle oro ni ede kan tabi omiiran. Gbolohun-; ni ipede ti o kun to si ni ise ti on je. OSE 3 EDE – Itesiwaju eko lori isori gbolohun gege bi ihun won. ASA – Igbagbo ati ero Yoruba nipa Ajinde leyin iku. A rii wi pe o fi ara pe aroko asapejuwe. daruko isori oro lede yoruba Bi apere: oro oruko, oro ise, oro apejuwe, oro aponle. O je ipede ti ko ni ju apola-oruko ati apola-ise kookan lo. IWE AKATILEWA. Bisi je iyan ni owuro. ORO ORUKO: Eyi ni n oro ti a n pe nkan. A pin gbolohun yii si ona meji, awon niyi; Olori awe gbolohun Ose Karun-un: Ede: Ise oro Apejuwe ati oro aponle ninu gbolohun Onka ni ede Yoruba – Ookanlelogorun-un de igba(101 – 200) Lara awon isori oro ti a to jo lati hun gbolohun ede Yoruba ni. OSE KEFAORI ORO-SILEBU NINU EDE YORUBA -ORIKI -IHUN -BATANI -ODO ATI APALA SILEBU AKOONU Odo silebu;ni apa to gbe se pataki julo ninu ihun silebu kookan. ISORI ORO, ONKA YORUBA LATI EGBAA DE EGBAARUN, ITUPALE GBOLOHUN ONIPON-ON-NA Saturday , 21 December 2024 Trending EKA ISE: EDE ORI ORO: ISE ORO ISE NINU GBOLOHUN Oro ise ni koko fonran to n toka isele tabi nnkan ti oluwa n se ninu gbolohun Oro ise ni opomulero gbolohun. Apola Oruko (noun phrase): okan ninu apola oro ti a hun po di gbolohun ni apola oruko. com. Ihun apola. Oro asopo ORO – ISE (VERB): Isori oro yii ni o maa n tola ohun ti oluwa se tabi toka isele ninu gbolohun. LITIRESO – Itupale asayn iwe lati ajo WAEC/NECO yan . Com. Eyi ni apeere ori-or, to je mo aroko oniroyin. Mo ti lo ki ore mi de Gbogbo ilu gbo pe oba waja Akekoo naa mura ki o le gbebun 4 ÈDÈ: Akoto; Awon oro ti a sunki [alanu= alaanu ati pataki yiyamo sidi oro ÀSÀ: Awon eya Yoruba, ounje won ati awon nnkan pataki nipa won LIT: Ipa ti litireso ko lawujo Yoruba. Ade n rin kanmokanmo bo. Lara awon isori oro ti a to jo lati hun gbolohun ede Yoruba ni. Lai si oro ise ninu gbolohun, gbolohun ko le ni itumo O maa Isori oro ninu ede Yoruba ni wonyii Oro-oruko Oro Aropo oruko Oro Aropo Afarajooruko Oro Eyan / Apejuwe Oro Ise Oro Aponle Oro Atokun Oro Asopo Oro-oruko: Eyi ni awon oro ti won le da duro ni ipo Oluwa, abo tabi eyan ninu EDE – ATUNYEWO AWON ISORI ORO-ORUKO, ORO AROPO ORUKO, ORO ISE, SISE ITUPALE GBOLOHUN KEKERE SI ISORI ORO Target Audience: First and foremost, this course is primarily for Senior secondary school students. Litireso: Awon ewi alohun ti o je mo esin abalaye iyere ifa, Sango pipe. EYA ORO ORUKO. Ede: Aranmo. Eto aabo ilu ati ipati awon obinrin n ko ninu eto ogun LITIRESO – Itupale asayn iwe lati ajo WAEC/NECO yan OSE KERINEYA AWE GBOLOHUN AFARAHEAKOONU:- Awe gbolohunafarahe Olori Awe GbolohunORISII AWE GBOLOHUN AFARAHEOrisii awe gbolohun afarahe meta ni o wa ninu ede Yoruba, awon meteeta ni: -(a) Awe Gbolohun Afarahe Asodoruko: eyi maa n sise oro oruko ninu gbolohun. IWULO ATI PATAKI IPOLOWO OJA EDE: ISORI ORO. Fun ORO – APONLE: Awon oro ti o maa n pon oro – ise le ninu gbolohun ni a pen i oro aponle. OSE KOKANLA EKA ISE: EDE AKOLE ISE: ISORI ORO NINU GBOLOHUN Isori oro ni abala ti a pin awon oro – Ede: Atunyewo Ihun Oro – Asa: Awon Orisa II – Ede: Orika Egbaa de Aadota Oke. Isori oro Yoruba oro-oruko (NOUN) oro-aropo oruko (PRONOUN) oro ise (VERB) oro Aropo oro apejuwe ( ADJECTIVE ) oro atoku EKA ISE: EDE ORI ORO: ISORI ORO – ORO AROPO-AFARAJORUKO Oro aropo afarajoruko je oro ti a n lo dipo oro oruko sugbon ti o fi ara jo oro oruko. Gbolohun onibo ni eyi ti a fi gbolohun kan ha ihun omiiran. Baba ra bata. Oro–ise je opomulero fun gbolohun laisi oro–ise ninu gbolohun ko le ni itumo. Isinku ni eye ikeyin ti a se fun oku logan ti o ku titi di akoko ti a fi sin. CLASS-; SS1 ILANA ISE OSOOSE FUN SAA KEJI Ose kinni- Ede-Atunyewo awon isori oro oro aropo oruko oro aropo afarajoruko oro atokun oro asopo oro-ise Asa- Oge sise Litireso-Itupale asayan iwe litireso Ose keji Ede- Awon isori gbolohun gege bi EDE – Iyato to wa laarin Oro Aponle ati Apola Aponle, alaye kikun. OSE KEJIORO AROPO ORUKO. ASA – Igbagbo Yoruba nipa Olodumare: i. Onka Yoruba je ona ti a n gba lati ka nnkan ni ona ti yoo rorun. Iwulo Ede Yoruba; Litireso Alohun to je mo esin; Week 7 – Onka Yoruba lati ookan de aadota (1-50) Bi asa se jeyo ninu ede Yoruba; Litireso Apileko; Week 8 – Onka lati ookan lelaadota de ogorun-un (51-100) Asa ati ohun-elo isomoloruko; Week 9 – Oriki ati liana kiko aroko Yoruba pelu apeere Ikini ni aarin eya Yoruba, ounje won ati bi won se n se won; Week 5 – Akoto ode oni . Yoruba lesson note for Junior Secondary School – Edudelight. Ose keta — Awon isori gbolohun Yoruba gege gi ise won OSE KERINAKORI ORO: - EYA GBOLOHUN EDE YORUBA AKOONU: -- Gbolohun eleyo oro ise - Gbolohun olopo oro ise - Gbolohun alakanpo - Gbolohun ase - Gbolohun ibeere Gbolohun ni ipede ti o kun. Gbólóhùn Eleyo oro Òrò ìse jé ìsòrí Òrò tí ó máa ń so ohun tí àwon Òrò orúko inú gbólóhùn se tàbí ohun tí ó selè sí Òrò orúko. Ede: Atunyewo gbogbo isori gbolohun. Olu fo aso. Tope kuru. Òrò-iṣe jé kòṣéemánìí nínú gbólóhùn, tí kò bá sí nínú gbólóhùn, gbólóhùn be ́èkò lé ní ìtumò kíkún. We provide curriculum-based lesson notes, week by week, as it is in the classrooms for thousands of student to read ahead and Ose kin-in-ni Ede-Atunyewo awon isori oro ninu ede Yoruba. Interested in downloading Third Term SS1 Yoruba Lesson Note, scroll up and click on the ‘order now’ button to OSE KARUN-UNORI-ORO-;Aayan Ogbufo AKOONUAayan ogbufo ni ise titumo ede kan si ede miiranKi ogbufo to le kogo ja ninu itumo ede, o gbodo mo tifun tedo ede Geesi , ki o si le tusu ede Yoruba naa de isale ikoko. Oro –ise Agbabo : – ni oro-ise ti a maa n lo abo pelu re ninu ede Yoruba. Odu ti kii saimo fun oloko ni isori-oro gbodo je fun ojulowo akekoo Ko marun sile ninu wuren ibeere Lo awon wuren ibeere naa ni gbolohun. Ti a ba yo oro ise: pon, ra, ro kuro ninu awon gbolohun oke wonyi, ko lee ni itumo. Ihun ede Yoruba da bi igba ti a bat i hun eni, a ni idi ti awon oro wonyi jo lona ti yoo fi le e mu itumo ti o gbamuse lowo, atun le fi we, tilo awon ohun elo ikole jo lorisirisi lona ti yoo le fi gbele ti o dara ti o si lewa jade. Olori Awe Gbolohun (Isori Awe Gbolohun) Awe Gbolohun Afarahe. ORI-ORO-;AWON ISORI GBOLOHUN EDE YORUBA GEGE BI ISE WON. Ohun kan naa ni opomulero to n toka isele inu gbolohun. iwe keta oju iwe 18 – 21 lati owo egbe akomolede ati asa Yoruba. Apola-ise le je: Oro-Ise Alaigbabo. EDE – Apola ninu gbolohun ede Yoruba: Apola oruko; Apole ise; Ihun apola; Awon isori oro ti a le ba pade labe apola oruko ati apola ise; ASA – Igbagbo Yoruba nipa Olodumare: Tani Olodumare Bi asa se jeyo ninu ede Yoruba. Apole ise. Oro oruko n sise oluwa: eyi ni oluse nnkan ninu gbolohun. AWE GBOLOHUN EDE YORUBA. Third Term SS1 Yoruba lesson note is ready for download. Ojo ro’. Oku eni ti igi yalu pa abbl. Ibeere gbolohun ni o ti maa n jeyo. oriki; ilo oro aropo oruko ninu gbolohun; asa About Press Copyright Contact us Creators Advertise Developers Terms Privacy Policy & Safety How YouTube works Test new features NFL Sunday Ticket Press Copyright Yoruba lesson notes for JSS3 (Basic 9) – Edudelight. Orisirisi ona ni a le pin gbolohun ede Yoruba si, Awon ni Oro – ise ni oro tabi akojopo oro ti o n toka si isele tabi nnkan ti Oluwa se ninu gbolohun. Awon naa ni:- Awon oro-aponle aiseda. oruko. Lo oro eyån ninü gbolohün ni kikån iv. AKOONU:- Silebu ni ege oro ti o kere julo ti eemi le gbe jade leekan soso Iye ohun ti o ba wa ninu oro ni iya silebu ti oro naa yoo ni. Oro aropo-oruko. Oro aropo oruko gege bi oruko maa n ropo oro oruko ninu gbolohun,mefa pere ni won,oro mii ko si le wo won laarin. Gbolohun onibo 7. Ki ni gbolohun (sentence)? Gbolohun ni ipede ti o kun, ti o ni itumo, ti o si ni ise ti o n je. Ihun apola oruko le je: Oro – Oruko kan soso pere: Ojo rǫ; Oro – Aropo oruko OSE KESAN-ANAWON ISORI GBOLOHUN YORUBA GEGE BI ISE WON. Salåyé ise ti oro eyan n se ninu gbolohun iii. eka ise: ede. ORO ISE (VERB) Oro ise ni oro ti o maa n today si isele ti o se laarin oluwa ati abo. Ara orisii gbolohun ni gbolohn olopo oro ise wa. LITERSO:- Kikea iwe itan apileko ere onise ti ijoba yan. Gbolohun re je eyo oro kan tabi akojopo. Odu ti kii saimo fun oloko ni isori-oro gbodo je fun ojulowo akekoo ede Yoruba. litireso: ewi alohun gege bi orisunironu yoruba. ÀSÀ: Iwulo OSE KKARUN-UN. Ede: Atunyewo Aroko ati aroko Atunyewo oro eya ninu gbolohun ede Yoruba: Ni opin idanilekoo, åwon akéköö yoo le: i. Tuntun latin ara isori oro miiran. Oro ise asebeere : – meji naa ni o wa ninu ede Yoruba, awon naa ni da ati nko. Gbólóhùn Eleyo oro-ise Gbólóhùn Olopo oro-ise Gbólóhùn IbeereGbólóhùn Ase . Gbolohun ede Yoruba nipa fifi oju ihun wo o ose keta: ede: isori oro: oriki oro ise; orisi oro ise; lilo ati dida won mo ninu gbolohun yoruba; asa: ere idaraya: ere osupa; ere ojojumo; ere ita gbangba; ere abele litireso: itupale asayan iwe ti ijoba yan. aroko je ohun ti a ro ti a si se akosile re . We provide curriculum-based lesson notes, week by week, as it is in the classrooms for thousands of student to read ahead and ninu gbolohun. Ki a to le se iroyin yori, a gbodo je eni ti o ni ife si gbigbo tabi kika iwe itan kekere. Gbolohun abode 2. Ami Ohun lori oro onisilebu meji SILEBU NINU EDE YORUBA Akoto ede yoruba ode-oni ONKA YORUBA LATI OOKAN DE AADOTA (1-50). Apeere Ade ra iwe Yoruba. Orisii Awe Gbolohun Afarahe. Àpẹẹrẹ:Bólú je èbàBàbá kọ ebèÈyà gbólóhùn. Awon iro odo silebu ni a maa n gbo ju ninu oro. Isori oro ise. oro aropo afarajoruko; lilo won ninu gbolohun asa: owo yiya. Orisiirisii Gbolohun inu ede Yoruba: 1. Ohun elo oku sin-sin. vei mpl xbwtq hrwyi urc erfux wtohxaj iyfhe kqt vyfx